Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Sáàmù 133:1-3

Orin Ìgòkè. Ti Dáfídì. 133  Wò ó! Ó mà dára o, ó mà dùn o, Pé kí àwọn ará máa gbé pa pọ̀ ní ìṣọ̀kan!+   Ó dà bí òróró dáradára ní orí,+ Èyí tí ń ṣàn wálẹ̀ sára irùngbọ̀n, Irùngbọ̀n Áárónì,+ Èyí tí ó ṣàn wálẹ̀ dé ọrùn ẹ̀wù rẹ̀.+   Ó dà bí ìrì+ Hámónì+ Tí ń sọ̀ kalẹ̀ sórí àwọn òkè ńlá Síónì.+ Nítorí pé ibẹ̀ ni Jèhófà pàṣẹ pé kí ìbùkún wà,+ Àní ìyè fún àkókò tí ó lọ kánrin.+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé