Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Sáàmù 131:1-3

Orin Ìgòkè. Ti Dáfídì. 131  Jèhófà, ọkàn-àyà mi kò ní ìrera,+Bẹ́ẹ̀ ni ojú mi kò ga fíofío;+Bẹ́ẹ̀ ni èmi kò rìn nínú àwọn ohun tí ó tóbi jù,+Tàbí nínú àwọn ohun tí ó jẹ́ àgbàyanu jù fún mi.+   Dájúdájú, mo ti tu ọkàn mi lára pẹ̀sẹ̀, mo sì ti mú un dákẹ́ jẹ́ẹ́+Bí ọmọ tí a já lẹ́nu ọmú, ọmọ tí ń bẹ lọ́wọ́ ìyá rẹ̀.+Bí ọmọ tí a já lẹ́nu ọmú ni ọ̀kan mi rí lára mi.+   Kí Ísírẹ́lì dúró de Jèhófà+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí dé àkókò tí ó lọ kánrin.+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé