Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Sáàmù 128:1-6

Orin Ìgòkè. 128  Aláyọ̀ ni gbogbo ẹni tí ó bẹ̀rù Jèhófà,+Tí ó ń rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.+   Nítorí tí ìwọ yóò jẹ làálàá ọwọ́ rẹ.+Aláyọ̀ ni ìwọ yóò jẹ́, yóò sì dára fún ọ.+   Aya rẹ yóò dà bí àjàrà tí ń so èso+Ní ìhà inú lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún ilé rẹ.Àwọn ọmọ rẹ yóò dà bí àwọn àgélọ́ igi ólífì+ yí tábìlì rẹ ká.   Wò ó! Bẹ́ẹ̀ ni a ó ṣe bù kún abarapá ọkùnrin+Tí ó bẹ̀rù Jèhófà.+   Jèhófà yóò bù kún ọ láti Síónì wá.+Kí ìwọ sì máa rí ire Jerúsálẹ́mù ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ,+   Kí o sì máa rí àwọn ọmọ-ọmọ rẹ.+Kí àlàáfíà wà lórí Ísírẹ́lì.+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé