Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Sáàmù 117:1, 2

117  Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;+ Ẹ gbóríyìn fún un, gbogbo ẹ̀yin agbo ìdílé.+   Nítorí pé inú rere rẹ̀ onífẹ̀ẹ́ sí wa jẹ́ alágbára ńlá;+ Òótọ́+ Jèhófà sì wà fún àkókò tí ó lọ kánrin. Ẹ yin Jáà!+

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé