Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

1 Kíróníkà 1:1-54

1  Ádámù,+Sẹ́ẹ̀tì,+Énọ́ṣì,+   Kénánù,+Máhálálélì,+Járédì,+   Énọ́kù,+Mètúsélà,+Lámékì,+   Nóà,+Ṣémù,+ Hámù+ àti Jáfẹ́tì.+  Àwọn ọmọkùnrin Jáfẹ́tì ni Gómérì àti Mágọ́gù+ àti Mádáì+ àti Jáfánì+ àti Túbálì àti Méṣékì+ àti Tírásì.+  Àwọn ọmọkùnrin Gómérì sì ni Áṣíkénásì+ àti Rífátì+ àti Tógámà.+  Àwọn ọmọkùnrin Jáfánì sì ni Élíṣáhì+ àti Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Ródánímù.+  Àwọn ọmọkùnrin Hámù ni Kúṣì+ àti Mísíráímù,+ Pútì+ àti Kénáánì.+  Àwọn ọmọkùnrin Kúṣì sì ni Sébà+ àti Háfílà àti Sábítà+ àti Ráámà+ àti Sábítékà.+ Àwọn ọmọkùnrin Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 10  Kúṣì fúnra rẹ̀ sì bí Nímírọ́dù.+ Òun ni ó bẹ̀rẹ̀ dídi alágbára ńlá ní ilẹ̀ ayé.+ 11  Ní ti Mísíráímù, ó bí Lúdímù+ àti Ánámímù àti Léhábímù àti Náfútúhímù+ 12  àti Pátírúsímù+ àti Kásílúhímù+ (láti inú àwọn tí àwọn Filísínì+ ti jáde) àti Káfítórímù.+ 13  Ní ti Kénáánì, ó bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ 14  àti àwọn ará Jébúsì+ àti àwọn Ámórì+ àti àwọn Gẹ́gáṣì+ 15  àti àwọn Hífì+ àti àwọn Ákì àti àwọn Sáínì+ 16  àti àwọn ọmọ Áfádì+ àti àwọn Sémárì+ àti àwọn ará Hámátì.+ 17  Àwọn ọmọkùnrin Ṣémù+ ni Élámù+ àti Áṣúrì+ àti Ápákíṣádì+ àti Lúdì+ àti Árámù, Àti Úsì àti Húlì àti Gétérì àti Máṣì.+ 18  Ní ti Ápákíṣádì, ó bí Ṣélà,+ Ṣélà alára sì bí Ébérì.+ 19  A sì bí ọmọkùnrin méjì fún Ébérì. Orúkọ ọ̀kan ni Pélégì,+ nítorí pé ní ọjọ́ rẹ̀ ni a pín ilẹ̀ ayé níyà; orúkọ arákùnrin rẹ̀ sì ni Jókítánì. 20  Ní ti Jókítánì, ó bí Álímódádì àti Ṣéléfì àti Hasamáfétì àti Jérà+ 21  àti Hádórámù àti Úsálì àti Díkílà+ 22  àti Óbálì àti Ábímáélì àti Ṣébà+ 23  àti Ófírì+ àti Háfílà+ àti Jóbábù;+ gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọkùnrin Jókítánì. 24  Ṣémù,+Ápákíṣádì,+Ṣélà,+ 25  Ébérì,+Pélégì,+Réù,+ 26  Sérúgù,+Náhórì,+Térà,+ 27  Ábúrámù,+ èyíinì ni, Ábúráhámù.+ 28  Àwọn ọmọkùnrin Ábúráhámù ni Ísákì+ àti Íṣímáẹ́lì.+ 29  Ìwọ̀nyí ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìdílé wọn: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì, Nébáótì+ àti Kídárì+ àti Ádíbéélì àti Míbúsámù,+ 30  Míṣímà àti Dúmà,+ Máásà, Hádádì+ àti Témà, 31  Jétúrì, Náfíṣì àti Kédémà.+ Àwọn wọ̀nyí ni ọmọkùnrin Íṣímáẹ́lì. 32  Ní ti àwọn ọmọkùnrin Kétúrà,+ wáhàrì Ábúráhámù,+ ó bí Símíránì àti Jókíṣánì àti Médánì+ àti Mídíánì+ àti Íṣíbákì+ àti Ṣúáhì.+ Àwọn ọmọkùnrin Jókíṣánì sì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 33  Àwọn ọmọkùnrin Mídíánì sì ni Eéfà+ àti Éférì àti Hánókù àti Ábíídà àti Élídáà.+ Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọkùnrin Kétúrà. 34  Ábúráhámù sì wá bí Ísákì.+ Àwọn ọmọkùnrin Ísákì ni Ísọ̀+ àti Ísírẹ́lì.+ 35  Àwọn ọmọkùnrin Ísọ̀ ni Élífásì, Réúẹ́lì+ àti Jéúṣì àti Jálámù àti Kórà.+ 36  Àwọn ọmọkùnrin Élífásì ni Témánì+ àti Ómárì, Séfò àti Gátámù, Kénásì+ àti Tímínà+ àti Ámálékì.+ 37  Àwọn ọmọkùnrin Réúẹ́lì ni Náhátì, Síírà, Ṣámáhì àti Mísà.+ 38  Àwọn ọmọkùnrin Séírì+ sì ni Lótánì àti Ṣóbálì àti Síbéónì àti Ánáhì+ àti Díṣónì àti Ésérì àti Díṣánì.+ 39  Àwọn ọmọkùnrin Lótánì sì ni Hórì àti Hómámù. Arábìnrin Lótánì sì ni Tímínà.+ 40  Àwọn ọmọkùnrin Ṣóbálì ni Álífánì àti Mánáhátì àti Ébálì, Ṣẹ́fò àti Ónámù.+ Àwọn ọmọkùnrin Síbéónì sì ni Áyà àti Ánáhì.+ 41  Àwọn ọmọkùnrin Ánáhì ni Díṣónì.+ Àwọn ọmọkùnrin Díṣónì sì ni Hémúdánì àti Éṣíbánì àti Ítíránì àti Kéránì.+ 42  Àwọn ọmọkùnrin Ésérì+ ni Bílíhánì àti Sááfánì àti Ákánì.+ Àwọn ọmọkùnrin Díṣánì ni Úsì àti Áránì.+ 43  Ìwọ̀nyí sì ni àwọn ọba tí ó jẹ ní ilẹ̀ Édómù+ kí ọba+ èyíkéyìí tó jẹ lórí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì: Bélà ọmọkùnrin Béórì, ẹni tí orúkọ ìlú ńlá rẹ̀ ń jẹ́ Díńhábà.+ 44  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Bélà kú, Jóbábù ọmọkùnrin Síírà+ láti Bósírà+ sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. 45  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Jóbábù kú, Húṣámù+ láti ilẹ̀ àwọn ará Témánì+ sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. 46  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Húṣámù kú, Hádádì+ ọmọkùnrin Bédádì, ẹni tí ó ṣẹ́gun Mídíánì+ ní pápá Móábù, sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú ńlá rẹ̀ sì ni Áfítì.+ 47  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Hádádì kú, Sámúlà láti Másírékà+ sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. 48  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Sámúlà kú, Ṣọ́ọ̀lù láti Réhóbótì+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. 49  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Ṣọ́ọ̀lù kú, Baali-hánánì ọmọkùnrin Ákíbórì+ sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀. 50  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Baali-hánánì kú, Hádádì sì bẹ̀rẹ̀ sí jọba ní ipò rẹ̀; orúkọ ìlú ńlá rẹ̀ sì ni Páù, orúkọ aya rẹ̀ sì ni Méhétábélì, ọmọbìnrin Mátírédì, ọmọbìnrin Mésáhábù.+ 51  Ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀, Hádádì kú. Àwọn séríkí Édómù sì ni séríkí Tímínà, séríkí Álíífà, séríkí Jététì,+ 52  séríkí Oholibámà, séríkí Éláhì, séríkí Pínónì,+ 53  séríkí Kénásì, séríkí Témánì, séríkí Míbúsárì,+ 54  séríkí Mágídíélì, séríkí Írámù.+ Ìwọ̀nyí ni séríkí+ Édómù.

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé