Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Bíbélì Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì | ÌWÉ MÍMỌ́ NÍ ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN

Ẹ́sítérì 10:1-3

10  Ahasuwérúsì Ọba sì tẹ̀ síwájú láti gbé òpò àfipámúniṣe+ lé orí ilẹ̀ náà àti àwọn erékùṣù+ òkun.  Ní ti gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ tí ó fi tokuntokun ṣe àti agbára ńlá rẹ̀ àti àlàyé tí ó ṣe pàtó nípa títóbi Módékáì,+ èyí tí ọba fi gbé e ga lọ́lá,+ a kò ha kọ wọ́n sínú Ìwé àlámọ̀rí+ àwọn àkókò ti àwọn ọba Mídíà àti Páṣíà?+  Nítorí Módékáì tí í ṣe Júù ni igbá-kejì+ Ahasuwérúsì Ọba, ó sì tóbi láàárín àwọn Júù, ògìdìgbó àwọn arákùnrin rẹ̀ sì tẹ́wọ́ gbà á, ó ń ṣiṣẹ́ fún ire àwọn ènìyàn rẹ̀, ó sì ń sọ̀rọ̀ àlàáfíà+ fún gbogbo ọmọ wọn.

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé