Ka Bíbélì lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì tàbí kó o wa ohùn tá a ti gbà sílẹ̀ jáde. Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun péye, ó sì rọrùn láti kà. A ti tẹ odindi rẹ̀ tàbí apá kan rẹ̀ jáde ní èdè tó lé ní ọgọ́fà [120]. A sì ti pín ẹ̀dà tó lé ní igba [200] mílíọ̀nù káàkiri.