Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

“Nítorí Èyí Ni Mo Ṣe Wá sí Ayé”

Wo ọ̀nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tí Jésù ń gbà kọ́ni bó ṣe ń fìgboyà jẹ́rìí sí òtítọ́.

Ó dá lórí Mátíù 21:​23-46; 22:​15-46.