Ọ̀rọ̀ wo? Ọkàn ta ni? Wò fídíò yìí kó o lè rí bí ìdáhùn àwọn ìbéèrè yìí ṣe ran bàbá kan lọ́wọ́ láti bójú tó ìdílé rẹ̀.