Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Nóà—Ó Bá Ọlọ́run Rìn

Olóòótọ́ èèyàn tó bá Ọlọ́run rìn ni Nóà. Àmọ́ kí nìdí tí Ọlọ́run fi ṣojúure sí Nóà? Kí ló mú kí tiẹ̀ yàtọ̀? Wo bí ohun tí Nóà ṣe ṣe ṣe òun àti ìdílé rẹ̀ láǹfààní, títí kan gbogbo wa lónìí.