Ó ń wu àwọn ọ̀rẹ́ méjì tórúkọ wọn ń jẹ́ Liz àti Megan láti rẹ́ni fẹ́, àmọ́ ọ̀nà tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn gbà ń wá a yàtọ̀.