Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ṣe ni ìtàn ìfẹ́ tí wọ́n máa ń sọ nínú ìwé àti èrò tí wọ́n máa ń gbé yọ nípa ìfẹ́ sábà máa ń fa ìrora ọkàn. Àmọ́, orí ìpìlẹ̀ Bíbélì tó yè kooro ni ìfẹ́ tòótọ́ máa ń dá lé.

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ìlànà Bíbélì lè ran àwọn Kristẹni lọ́wọ́ láti yan ọkọ tàbí yan aya rere, á sì tún jẹ́ kí wọ́n lè maa fi ìfẹ́ tòótọ́ hàn síra tí wọ́n bá ti fẹ́ra wọn délé tán.

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?​—Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀

O lè jàǹfààní nínú àwọn ìlànà tó wà nínú fídíò yìí tí o kò bá gbàgbé pé ìyàtọ̀ wà nínú àṣà ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan tó bá kan ọ̀ràn ìfẹ́rasọ́nà tó máa ń yọrí sí ìgbéyàwó.