Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run ti fi Jésù ṣe Olúwa àti Kristi? Rán ara rẹ létí àwọn ẹ̀rí pàtàkì náà.