Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’

Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́, a lè bẹ̀rẹ̀ sí í ṣiyèméjì, kí ìgbàgbọ́ wa má sì lágbára mọ́. Mú kí ìgbàgbọ́ tó o ní nínú Jésù, Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí àti Ọba Ìjọba Ọlọ́run túbọ̀ lágbára sí i.

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá I)

Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run ti fi Jésù ṣe Olúwa àti Kristi?

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá II)

Wo ohun tó máa jẹ́ kó o nígbàgbọ́ tó lágbára nínú Jésù.