Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

“Jèhófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”

Wo bí Hesekáyà ṣe borí ìṣòro lọ́tùn-lósì kó lè ṣe ìpinnu tó dá lórí ìgbàgbọ́ àti ìdúróṣinṣin, tó sì tipa bẹ́ẹ̀ fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ fáwọn ọmọ ìlú rẹ̀ àti gbogbo àwọn tó ń sin Jèhófà lónìí.