Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Fi Àwọn Ìlànà Bíbélì Sílò

Wàá Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n Tó O Bá Ń Gbàmọ̀ràn

Wàá Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n Tó O Bá Ń Gbàmọ̀ràn

Ọ̀dọ́ kan tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di alàgbà ló fún Byong Soo nímọ̀ràn, àmọ́ ẹnì kan ràn án lọ́wọ́ láti máa fi ìmọ̀ràn tí wọ́n bá fún un látinú Bíbélì sílò, kó sì gbà pé ọ̀dọ̀ Jèhófà gan-an ló ti wá.