Ọ̀jọ̀gbọ́n ni Petr tó bá dọ̀rọ̀ ìmọ̀ nípa èrò orí èèyàn. Wo bí ìlànà àdáyébá kan tó kọ́ nípa ẹ̀ ṣe mú kó tún inú rò lórí ohun tó gbà gbọ́.