Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Massimo Tistarelli: Ẹni Tó Ń Ṣe Rọ́bọ́ọ̀tì Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́

Massimo Tistarelli: Ẹni Tó Ń Ṣe Rọ́bọ́ọ̀tì Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́

Massimo Tistarelli mọ bí wọ́n ṣe ń ṣe rọ́bọ́ọ̀tì, àmọ́ bí wọ́n ṣe ń fi kọ̀ǹpútà dá ojú èèyàn mọ̀ gan-an ni iṣẹ́ rẹ̀. Ó gbà pé ohun tí sáyẹ́ǹsì bá sọ labẹ́ gé, àmọ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí í tún èrò ẹ̀ pa lórí ọ̀rọ̀ ẹfolúṣọ̀n.