Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò Lóde Ẹ̀rí

Ṣé O Fẹ́ Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀?

Ṣé O Fẹ́ Gbọ́ Ìròyìn Ayọ̀?

Pẹ̀lú bó ṣe jẹ́ pé ìròyìn burúkú là ń gbọ́ káàkiri yìí, ibo la ti lè gbọ́ ìròyìn ayọ̀? Fídíò yìí sọ ohun tó wà nínú ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!

 

Mọ Púpọ̀ Sí I

ÌRÒYÌN AYỌ̀ LÁTỌ̀DỌ̀ ỌLỌ́RUN!

Kí Ni Ìròyìn Ayọ̀ Náà?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìròyìn tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ìdí tó fi jẹ́ kánjúkánjú àti ohun tó yẹ kó o ṣe.