Àkópọ̀ ohun tó wà nínú àsọtẹ́lẹ̀ Sekaráyà, tó sọ àwọn nǹkan pàtó nípa bí Mèsáyà ṣe máa dé, bí wọ́n ṣe máa hùwà ọ̀dàlẹ̀ sí i àti bí wọ́n ṣe máa pa á.