Wàá kọ́ nípa ìwé Sáàmù, ìyẹn ìwé Bíbélì tó ń tuni nínú lóde òní, tó sì ń fúnni nírètí fún ọjọ́ iwájú.