Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Fídíò Tó Nasẹ̀ Ìwé Bíbélì

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Máàkù

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Máàkù

Ṣàyẹ̀wò àkọsílẹ̀ ìwé Ìhìn Rere Máàkù. Ó dá lórí iṣẹ́ òjíṣẹ́ Jésù, àmọ́ ó ṣe ṣókí ó sì sojú abẹ níkòó.