Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Fídíò Tó Nasẹ̀ Ìwé Bíbélì

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sítérì

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sítérì

Wo fídíò yìí kó o lè mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó wà nínú ìwé Ẹ́sítérì, ibi táwọn ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti ṣẹlẹ̀, ohun tí ìwé náà sọ nípa bí Ẹ́sítérì ṣe fìgboyà gbèjà àwọn èèyàn Ọlọ́run àti bí ìwé yìí ti ṣe pàtàkì tó.