Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Fídíò Tó Nasẹ̀ Ìwé Bíbélì

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sírà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sírà

Kọ́ nípa àwọn ohun pàtàkì tó wà nínú ìwé Ẹ́sírà bó ṣe wà nínú Bíbélì, ìyẹn ìtàn bí ìjọsìn tòótọ́ ṣe padà bọ́ sípò lẹ́yìn tí àwọn Júù kúrò nígbèkùn ní Bábílónì.