Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

“Máa Retí Ohun Tí A Kò Rí”

“Máa Retí Ohun Tí A Kò Rí”

“Máa Retí Ohun Tí A Kò Rí”

Nígbà ayé Jóòbù, ó dojú kọ àdánwò ìwà títọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn. Àwọn àdánwó náà sì kọjá kèremí. Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ìdílé Bannister, kó o lè rí bí àwọn náà ṣe dojú kọ àwọn àdánwò ìgbàgbọ́ tó jọ ti Jóòbù. Nígbẹ̀yìngbẹ́yín, kí ló ran ìdílé yìí lọ́wọ́ tí wọn ò fi jẹ́ káwọn ìṣòro náà ba àjọṣe wọn pẹ̀lú Ọlọ́run jẹ́?