Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Pa Da Sọ́dọ̀ Jèhófà

Jèhófà ń wá àwọn àgùntàn rẹ̀ tó sọnù, ó sì ń rọ̀ ọ́ pé kó o pa dà sọ́dọ̀ òun.

Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí

Ìgbìmọ̀ Olùdarí kọ lẹ́tà yìí láti rọ àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run tí wọ́n ti fi ètò rẹ̀ sílẹ̀ pé kí wọ́n pa dà wá sílé.

APÁ 1

“Èyí Tí Ó Sọnù Ni Èmi Yóò Wá”

Ǹjẹ́ Ọlọ́run máa ń wo ẹni tó ti fètò rẹ̀ sílẹ̀ bí ẹni tó ti lọ pátápátá?

APÁ 2

Àníyàn Ìgbésí Ayé—“A Há Wa Gádígádí ní Gbogbo Ọ̀nà”

Tí ìrẹ̀wẹ̀sì bá bá ẹ torí pé o ò lè ṣe tó bó o ṣe ń ṣe tẹ́lẹ̀ nínú iṣẹ́ ìsìn Jèhófà, ohun kan wà tó o lè ṣe táá jẹ́ kí Jèhófà fagbára rẹ̀ ràn ẹ́ lọ́wọ́.

APA 3

Ẹ̀dùn Ọkàn—Bí Ẹnì Kan Bá Ṣẹ̀ Wá

Mẹ́ta lára àwọn ìlànà Bíbélì máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ nígbà tí Kristẹni bíi tìẹ bá ṣẹ̀ ọ́.

APÁ 4

Ẹ̀bi Ẹ̀ṣẹ̀—‘Wẹ̀ Mí Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀ṣẹ̀ Mi’

Báwo lo ṣe lè ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ kí ara sì tù ẹ́?

APA 5

Pa dà Sọ́dọ̀ ‘Olùṣọ́ Àgùntàn àti Alábòójútó Rẹ’

Ibo ni kí n ti bẹ̀rẹ̀ tí mo bá fẹ́ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà? Ojú wo làwọn ará á máa fi wò mí?

Ìparí

Ǹjẹ́ o máa ń rántí àwọn àkókò alárinrin tó o ní pẹ̀lú àwọn èèyàn Jèhófà?