Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú
  • Ẹnìkan tí ìwọ fẹ́ràn ha ti sùn nínú ikú bí?

  • Ìwọ ha ṣì ń kẹ́dùn bí?

  • Ìwọ ha ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ nínú kíkojú ẹ̀dùn-ọkàn rẹ bí?

  • Ìrètí ha wà fún àwọn òkú bí?

  • Bí ó bá wà, kí ni ó jẹ́?

  • Báwo ni ó ṣe lè dá wa lójú?

Nínú ìwé pẹlẹbẹ yìí, irú àwọn ìbéèrè bẹ́ẹ̀ yóò rí ìdáhùn tí ń tuninínú láti inú Bibeli. A rọ̀ ọ́ láti kà á dáradára.