Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìbẹ̀rẹ̀ Ìwé

Ìbẹ̀rẹ̀ Ìwé

“Kí ìwọ sì fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo okun rẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ. Kí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tí mo ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sì wà ní ọkàn rẹ, kí ìwọ sì fi ìtẹnumọ́ gbìn wọ́n sínú àwọn ọmọ rẹ, kí o sì máa sọ̀rọ̀ nípa wọn nígbà tí o bá jókòó nínú ilé rẹ àti nígbà tí o bá ń rìn ní ojú ọ̀nà àti nígbà tí o bá dùbúlẹ̀ àti nígbà tí o bá dìde.”DIUTARÓNÓMÌ 6:5-7