Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016

 ÀWỌN OHUN PÀTÀKÌ TÓ ṢẸLẸ̀ LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ

Báwo Ni Iṣẹ́ Ṣe Ń Lọ Sí Ní Warwick?

Báwo Ni Iṣẹ́ Ṣe Ń Lọ Sí Ní Warwick?

IBI TÍ iṣẹ́ dé ní oríléeṣẹ́ wa tuntun tá à ń kọ́ sí Warwick, nílùú New York fi hàn pé Jèhófà lọ́wọ́ sí i torí à ń rí ìtìlẹyìn rẹ̀ lọ́nà tó kàmàmà.

Arákùnrin Anthony Morris tó wà lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ pé táyọ̀tayọ̀ la máa fi kí àwọn ará káàbọ̀ sí Warwick tí iṣẹ́ bá parí níbẹ̀.

Àbáwọlé sí oríléeṣẹ́ wa tuntun ní Warwick, nílùú New York