NÍGBÀ tó fi máa di August 31, 2015, a ti túmọ̀ Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lápá kan tàbí lódindi sí èdè mọ́kàndínláàádóje [129]. Bíbélì yìí tún wà lórí Ìkànnì jw.org lédè mọ́kàndínláàádóje [129], méje lára wọn sì jẹ́ èdè àwọn adití. Àwọn tá a mú jáde lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2015 la tò sísàlẹ̀ yìí: