Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Iwe Odoodun Awa Elerii Jehofa​—2015

 ÀWỌN OHUN PÀTÀKÌ TÓ ṢẸLẸ̀ LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ

Ise N Yara Te Siwaju Niluu Warwick

Ise N Yara Te Siwaju Niluu Warwick

BÍ ARA àwọn èèyàn ṣe ń yá gágá, bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ ń lọ ní pẹrẹu níbi tá a fẹ́ fi ṣe oríléeṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìlú Warwick, ìpínlẹ̀ New York, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin ló ti yááfì ọ̀pọ̀ nǹkan kí wọ́n lè wá kópa nínú iṣẹ́ ìkọ́lé náà. Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ wọn ló ń sọ pé, “A ò ní jẹ́ kí ohunkóhun gba àǹfààní tá a ní láti ṣiṣẹ́ níbí mọ́ wa lọ́wọ́.” Ẹ jẹ́ ká jọ wo ohun tó ń lọ nílùú Warwick.