Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?

Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?

Ṣé o rò pé . . .

  • inú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ni?

  • àbí inú ìmọ̀ ọgbọ́n orí?

  • àbí inú Bíbélì?

 Ọ̀KAN LÁRA ÀWỌN TÓ KỌ BÍBÉLÌ SỌ FÚN ỌLỌ́RUN PÉ

“Mú mi lóye . . . Òtítọ́ ni . . . ọ̀rọ̀ rẹ.”Sáàmù 119:144, 160, Ìtumọ̀ Ayé Tuntun.

Bíbélì ń dáhùn ìbéèrè ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn.

Ṣé wàá fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?

Ìkànnì jw.org/yo máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

KA ohun tó wà lórí ìkànnì náà

 ÈWO LÁRA ÀWỌN ÌBÉÈRÈ PÀTÀKÌ YÌÍ LÓ Ń JẸ Ọ́ LỌ́KÀN JÙ LỌ?

Wàá rí ìdáhùn látinú Bíbélì sí àwọn ìbéèrè yìí lórí ìkànnì jw.org/yo.

(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ › OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)