Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2017-2018​—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe

Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí tí a ti máa gbọ́ àsọyé látẹnu alábòójútó àyíká.

Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Ṣe Ohun Tó Dára!

Kí nìdí tó fi ṣòro láti ṣe ohun tó dára, àmọ́ kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ láti ṣàṣeyọrí?

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìbéèrè yìí, a sì máa dáhùn wọn nígbà tí ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.