Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2017-​2018​—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe

Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí tí a ti máa gbọ́ àsọyé látẹnu aṣojú ẹ̀ka ọ́fí ìsì.

Má Sọ̀rètí Nù Bó O Ṣe Ń Mú Òfin Kristi Ṣẹ!

A máa mọ ohun tí Òfin Kristi túmọ̀ sí àti bá a ṣe lè mú un ṣẹ.

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìbéèrè yìí, a sì máa dáhùn wọn nígbà tí ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.