Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ta Ni Òǹṣèwé Bíbélì?

Ta Ni Òǹṣèwé Bíbélì?

Tó bá jẹ́ pé èèyàn ló kọ ọ́, kí wá nìdí tí wọ́n fi ń pe Bíbélì ní “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”? (1 Tẹsalóníkà 2:13) Báwo ni Ọlọ́run ṣe lè fi èrò rẹ̀ sínú àwọn èèyàn?