Bíbélì sọ pé “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” ni àti pé Ọlọ́run “kò lè purọ́.” (1 Tẹsalóníkà 2:13; Títù 1:2) Ṣé òótọ́ ni, àbí ọ̀rọ̀ ìtàn àròsọ àti àwọn ìtàn àtẹnudẹ́nu ló kúnnú Bíbélì?