Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú

Ǹjẹ́ O Ti Ronú Nípa Ìbéèrè Yìí Rí?

Àwọn èèyàn tó pọ̀ rẹpẹtẹ ló rí ìdáhùn tó tẹ́ wọn lọ́rùn sí ìbéèrè wọ̀nyí nígbà tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ nínú Ìwé Mímọ́. Ìwọ náà lè rí ìdáhùn tí yóò tẹ́ ọ lọ́rùn.

Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i, lo sí ìkànnì www.jw.org/yo, tàbí kó o kàn sí ẹni tó fún ọ ní ìwé yìí.