Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?

Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀ Inú Bíbélì

Àtẹ Àwọn Ọjọ́ Ìṣẹ̀lẹ̀ Inú Bíbélì
 1. ‘Ní àtètèkọ́ṣe . . .’

 2. 4026 Ṣ.S.K. Ìṣẹ̀dá Ádámù

 3.  3096 Ṣ.S.K. Ádámù Ikú

 4. 2370 Ṣ.S.K. Omi bẹ̀rẹ̀ sí í ya lulẹ̀

 5.  2018 Ṣ.S.K. A bí Ábúráhámù

 6. 1943 Ṣ.S.K. Májẹ̀mú Ábúráhámù

 7. 1750 Ṣ.S.K. Wọ́n ta Jósẹ́fù lẹ́rú

 8.  ṣáájú 1613 Ṣ.S.K. Àdánwò Jóòbù

 9. 1513 Ṣ.S.K. Ìjáde kúrò ní Íjíbítì

 10.  1473 Ṣ.S.K. Jóṣúà kó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wọ ilẹ̀ Kénáánì

 11. 1467 Ṣ.S.K. Wọ́n parí ṣíṣẹ́gun àwọn ibi pàtàkì-pàtàkì nílẹ̀ Kénáánì

 12. 1117 Ṣ.S.K. A fòróró yan Sọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí ọba

 13.  1070 Ṣ.S.K. Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú Ìjọba

 14. 1037 Ṣ.S.K. Sólómọ́nì di ọba

 15. 1027 Ṣ.S.K. Wọ́n parí kíkọ́ tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù

 16. nǹkan bí 1020 Ṣ.S.K. Wọ́n parí kíkọ ìwé Orin Sólómọ́nì

 17. 997 Ṣ.S.K. A pín ìjọba Ísírẹ́lì sí méjì

 18.  nǹkan bí 717 Ṣ.S.K. Àkójọ àwọn Òwe parí

 19. 607 Ṣ.S.K. Àwọn ọmọ ogun pa Jerúsálẹ́mù run; ìkónígbèkùn lọ sí Bábílónì bẹ̀rẹ̀

 20.  539 Ṣ.S.K. Kírúsì ṣẹ́gun ìlú Bábílónì

 21. 537 Ṣ.S.K. Àwọn Júù tó wà nígbèkùn padà sí Jerúsálẹ́mù

 22.  455 Ṣ.S.K. A tún odi Jerúsálẹ́mù kọ́; ọ̀sẹ̀ 69 ti ọdún bẹ̀rẹ̀

 23. Lẹ́yìn 443 Ṣ.S.K. Málákì parí ìwé àsọtẹ́lẹ̀ rẹ̀

 24.  nǹkan bí 2 Ṣ.S.K. Ìbí Jésù

 25.  29 S.K. A batisí Jésù àti Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù nípa Ìjọba Ọlọ́run

 26. 31 S.K. Jésù yan àwọn àpọ́sítélì rẹ̀ méjìlá; ó ṣe Ìwàásù Lórí Òkè

 27.  32 S.K. Jésù jí Lásárù dìde

 28.  Nísàn 14, 33 S.K. Wọ́n kan Jésù mọ́gi (Oṣù Nísàn bọ́ sí apá kan oṣù March àti apá kan oṣù April)

 29. Nísàn 16 33 S.K. Ọlọ́run jí Jésù dìde

 30. Sífánì 6, 33 S.K. Pẹ́ńtíkọ́sì; ìtújáde ẹ̀mí mímọ́ (Oṣù Sífánì bọ́ sí apá kan oṣù May àti apá kan oṣù June)

 31. 36 S.K. Kọ̀nílíù di Kristẹni

 32.  nǹkan bí 47 sí 48 S.K. Ìrìn àjò àkọ́kọ́ tí Pọ́ọ̀lù rìn láti lọ wàásù

 33. nǹkan bí 49 sí 52 S.K. Ìrìn àjò ẹlẹ́ẹ̀kejì tí Pọ́ọ̀lù rìn láti lọ wàásù

 34. nǹkan bí 52 sí 56 S.K. Ìrìn àjò ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Pọ́ọ̀lù rìn láti lọ wàásù

 35.  60  sí 61 S.K. Pọ́ọ̀lù kọ lẹ́tà nígbà tó ń ṣẹ̀wọ̀n ní Róòmù

 36. ṣáájú 62 S.K. Jákọ́bù, iyèkan Jésù kọ lẹ́tà rẹ̀

 37.  66 S.K. Àwọn Júù ṣọ̀tẹ̀ sí ìlú Róòmù

 38. 70 S.K. Àwọn ará Róòmù pa Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀ run

 39.  nǹkan bí 96 S.K. Jòhánù kọ ìwé Ìṣípayá

 40. nǹkan bí 100 S.K. Ikú Jòhánù, ẹni tó gbẹ̀yìn lára àwọn àpọ́sítélì