Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ohun Tó Wà Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 ÌBÉÈRÈ 4

Ṣé Bíbélì Máa Ń Tọ̀nà Tó Bá Sọ̀rọ̀ Nípa Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì?

Ṣé Bíbélì Máa Ń Tọ̀nà Tó Bá Sọ̀rọ̀ Nípa Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì?

“Ó na àríwá sórí ibi ṣíṣófo, ó so ilẹ̀ ayé rọ̀ sórí òfo.”

Jóòbù 26:7

“Gbogbo ọ̀gbàrá ìgbà òtútù ń ṣàn lọ sínú òkun, síbẹ̀síbẹ̀ òkun kò kún. Ibi tí àwọn ọ̀gbàrá ìgbà òtútù ti ń ṣàn jáde lọ, ibẹ̀ ni wọ́n ń padà sí, kí wọ́n bàa lè ṣàn jáde lọ.”

Oníwàásù 1:7

“Ẹnì kan wà tí ń gbé orí òbìrìkìtì ilẹ̀ ayé.”

Aísáyà 40:22