Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2017

Switzerland

À Ń Wàásù A sì Ń Kọ́ni Kárí Ayé

À Ń Wàásù A sì Ń Kọ́ni Kárí Ayé

 KÁRÍ AYÉ

  • ILẸ̀ 240

  • IYE AKÉDE 8,340,847

  • ÀRÒPỌ̀ WÁKÀTÍ TÁ A FI WÀÁSÙ 1,983,763,754

  • IYE ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ 10,115,264

NÍ APÁ YÌÍ

Áfíríkà

Ka ìrírí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní àtàwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ bí wọ́n ṣe ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lórílẹ̀-èdè Gánà, Gíní-Bìsaù, Làìbéríà, Màláwì, Tógò àti Siria Lóònù.

Àwọn Ilẹ̀ Amẹ́ríkà

Àwọn ìrírí láti orílẹ̀-èdè Brazil, Haiti, Mẹ́síkò, Amẹ́ríkà àti Fẹnẹsúélà.

Éṣíà àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn

Àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lórílẹ̀-èdè Hong Kong, Mòǹgólíà, Philippines àti Siri Láńkà.

Yúróòpù

Ka ìrírí àwọn èèyàn ní orílẹ̀-èdè Azerbaijan, Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Bọ̀géríà, Jọ́jíà, Denmark, Hungary, Nọ́wè àti Ukraine.

Oceania

Àwọn ìrírí àtàwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lórílẹ̀-èdè Ọsirélíà, Guam, New Caledonia, Papua New Guinea àti Timor-Leste.