Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2016

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2016
 • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 89

 • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 240

 • Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 119,485

 • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 20,085,142

 • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 18,013

 • Góńgó Akéde: 8,340,847

 • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 8,132,358

 • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2015: 145,079

 • Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 264,535

 • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 459,393

 • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Lóṣooṣù: 1,157,017

 • Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 1,983,763,754

 • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣooṣù: 10,115,264

Ní ọdún iṣẹ́ ìsìn 2016, ó ju igba ó lé mẹ́tàlá [213] mílíọ̀nù owó dọ́là táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó arìnrìn-àjò lẹ́nu iṣẹ́ wọn. Bákan náà, kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún mọ́kàndínlógún ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ àti méjìdínlógún [19,818]. Gbogbo wọn wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.