Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 18-B

Owó àti Ìdíwọ̀n

Owó àti Ìdíwọ̀n
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù

Gírà (1⁄20 ṣékélì)

0.57 gíráàmù / 0.01835 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Gírà 10 = Bíkà 1

Bíkà

5.7 gíráàmù / 0.1835 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Bíkà 2 = Ṣékélì 1

Píìmù

7.8 gíráàmù / 0.2508 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Píìmù 1 = 2⁄3 ṣékélì

Ìdiwọ̀n ṣékélì

Ṣékélì

11.4 gíráàmù / 0.367 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

50 ṣékélì = Mínà 1

Mínà

570 gíráàmù / 18.35 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

60 mínà = Tálẹ́ńtì 1

Tálẹ́ńtì

34.2 kìlógíráàmù / 1,101 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Dáríkì (ti Páṣíà, wúrà)

8.4 gíráàmù / 0.27 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Ẹ́sírà 8:27

Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì

Lẹ́pítónì (Ti àwọn Júù, bàbà tàbí búróǹsì)

1⁄2 Kúádíránì

Lúùkù 21:2

Kúádíránì (Ti àwọn ará Róòmù, bàbà tàbí búróǹsì)

2 Lẹ́pítónì

Mátíù 5:26

Ásáríò (Ti àwọn Róòmù àtàwọn ìlú abẹ́ wọn, bàbà tàbí búróǹsì)

Kúádíránì 4

Mátíù 10:29

Dínárì (Ti àwọn Róòmù, fàdákà)

Kúádíránì 64

3.85 gíráàmù / 0.124 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Mátíù 20:10

Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (Wákàtí 12)

 Dírákímà (Tí àwọn Gíríìkì, fàdákà)

3.4 gíráàmù / 0.109 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Lúùkù 15:8

Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (Wákàtí 12)

Dírákímà méjì alápapọ̀ (Tí àwọn Gíríìkì, fàdákà)

Dírákímà 2

6.8 gíráàmù / 0.218 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Mátíù 17:24

Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 2

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Áńtíókù

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Tírè (Ṣékélì fàdákà ti Tírè)

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ (Tí àwọn Gíríìkì, fàdákà; wọ́n tún ń pè é ní owó sítátà fàdákà)

Dírákímà 4 13.6 gíráàmù / 0.436 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Mátíù 17:27

Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 4

Mínà

100 dírákímà

340 gíráàmù / 10.9 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Lúùkù 19:13

= nǹkan bí owó iṣẹ́ 100 ọjọ́

Tálẹ́ńtì

60 mínà

20.4 kìlógíráàmù / 654 ọ́ǹsì tọ́ọ̀nù

Mátíù 18:24

Ìṣípayá 16:21

= nǹkan bí owó iṣẹ́ ọdún 19

Ìwọ̀n Pọ́n-ùn (ti àwọn ará Róòmù)

327 gíráàmù / 11.5 ọ́ǹsì

Jòhánù 12:3

‘Ìwọ̀n pọ́n-ùn kan òróró onílọ́fínńdà, ojúlówó náádì’