Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 16-B

Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá 2)

Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá 2)
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Nísàn 12

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́

 • Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 13

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá

 • Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 14

 ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 • Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá

 • Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì

 • Ó ní kí Júdásì máa lọ

 • Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀

 • Júdásì fi í hàn, wọ́n sì mú un ní ọgbà Gẹtisémánì

 • •Àwọn àpọ́sítélì sá

 • Ó jẹ́jọ́ níwájú Sànhẹ́dírìn nílé Káyáfà

 • Pétérù sẹ́ Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Ó pa dà jẹ́jọ́ níwájú Sànhẹ́dírìn

 • Wọ́n mú un lọ sọ́dọ̀ Pílátù, lẹ́yìn náà sọ́dọ̀ Hẹ́rọ́dù, wọ́n tún dá a pa dà sọ́dọ̀ Pílátù

 • Wọ́n dájọ́ ikú fún un, wọ́n sì pa á ní Gọ́gọ́tà

 • Ó kú ní nǹkan bí aago mẹ́ta ọ̀sán

 • Wọ́n gbé òkú rẹ̀ lọ sin

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 15 (Sábáàtì)

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ ibojì Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 16

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 • Wọ́n ra èròjà atasánsán púpọ̀ sí i tí wọ́n á fi sin òkú rẹ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Ó jíǹde

 • Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀