Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 19

Kàlẹ́ńdà Àwọn Hébérù

Kàlẹ́ńdà Àwọn Hébérù
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

NÍSÀN (ÁBÍBÙ) March—April

14 Ìrékọjá

15-21 Àkàrà Aláìwú

16 Ọrẹ ẹbọ àkọ́so èso

Òjò àti yìnyín tó yọ́ mú kí odò Jọ́dánì kún sí i

Ọkà Báálì

ÍÍYÀ (SÍFÌ) April—May

14 Ìrékọjá Àdáṣe

Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn bẹ̀rẹ̀, kì í sí kùrukùru

Àlìkámà

SÍFÁNÌ May—June

6 Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (Pẹ́ńtíkọ́sì)

Ooru ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn, ojú ọjọ́ mọ́ kedere

Àlìkámà, àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́

TÁMÚSÌ

 

Ooru pọ̀ sí i, ìrì púpọ̀ máa ń sẹ̀ lágbègbè yìí

Àkọ́pọ́n èso àjàrà

ÁBÌ July—August

 

Ìgbà tí ooru pọ̀ jù lọ

Àwọn èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn

ÉLÚLÌ August—September

 

Ooru ṣì wà

Èso déètì, ọ̀pọ̀tọ́ àti àjàrà

TÍṢÍRÌ (ÉTÁNÍMÙ) September—October

1 Fífun kàkàkí

10 Ọjọ́ Ètùtù

15-21 Àjọyọ̀ Àtíbàbà

22 Àpéjọ ọ̀wọ̀

Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn parí, òjò àkọ́rọ̀ bẹ̀rẹ̀

Títúlẹ̀

HÉṢÍFÁNÙ (BÚLÌ) October—November

 

Òjò winniwinni

Èso ólífì

KÍSÍLÉFÌ November—December

25 Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́

Òjò ń pọ̀ sí i, omi dídì, yìnyín bo òkè

Agbo ẹran kò sí níta mọ́

TÉBÉTÌ December—January

 

Ìgbà tí òtútù mú jù lọ, ìgbà òjò, yìnyín bo òkè

Ohun ọ̀gbìn ń hù

ṢÉBÁTÌ January—February

 

Òtútù ò fi bẹ́ẹ̀ mú mọ́, òjò ṣì ń rọ̀

Álímọ́ńdì yọ ìtànná

ÁDÁRÌ February—March

14, 15 Púrímù

Ààrá ń sán lemọ́lemọ́, yìnyín sì ń já bọ́

Ọ̀gbọ̀

FÍÁDÀ March

Oṣù kẹtàlá máa ń wà March ní ìgbà méje lọ́dún 19