Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 4-E

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Títayọ tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá 3) àti ní Jùdíà

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Títayọ tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá 3) àti ní Jùdíà
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, lẹ́yìn Ìrékọjá

Òkun Gálílì; Bẹtisáídà

Jésù wọkọ̀ ojú omi lọ sí Bẹtisáídà, ó kìlọ̀ nípa ìwúkàrà àwọn Farisí; ó la ojú ọkùnrin afọ́jú kan

16:5-12

8:13-26

   

Àgbègbè Kesaréà ti Fílípì

Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba Ọlọ́run; ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú àti àjíǹde rẹ̀

16:13-28

8:27–9:1

9:18-27

 

Ó lè jẹ́ ní Òkè Hámónì

Ìyípadà ológo; Jèhófà sọ̀rọ̀

17:1-13

9:2-13

9:28-36

 

Àgbègbè Kesaréà ti Fílípì

Ó lé ẹ̀mí èṣù jáde lára ọmọdékùnrin kan

17:14-20

9:14-29

9:37-43

 

Gálílì

Ó tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀

17:22, 23

9:30-32

9:43-45

 

Kápánáúmù

Ó fi owó tí wọ́n rí lẹ́nu ẹja san owó orí

17:24-27

     

Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba Ọlọ́run; àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù àti ti ẹrú tí kò dárí jini

18:1-35

9:33-50

9:46-50

 

Gálílì sí Samáríà

Ó ń lọ sí Jerúsálẹ́mù, ó sọ fáwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n yááfì gbogbo nǹkan torí Ìjọba Ọlọ́run

8:19-22

 

9:51-62

7:2-10

Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Lọ Ṣe ní Jùdíà

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn

Jerúsálẹ́mù

Ó kọ́ni níbi Àjọyọ̀ náà; wọ́n rán àwọn onípò àṣẹ pé kí wọ́n wá mú un

     

7:11-52

Ó sọ pé “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé”; ó la ojú ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú

     

8:12–9:41

Ó lè jẹ́ ní Jùdíà Ó rán àwọn 70 jáde; wọ́n fi ìdùnnú pa dà

   

10:1-24

 

Jùdíà; Bẹ́tánì

Àpèjúwe ará Samáríà; ó lọ sí ilé Màríà àti Màtá

   

10:25-42

 

Ó lè jẹ́ ní Jùdíà

Ó tún kọ́ wọn ní àdúrà àwòṣe; àpèjúwe ọ̀rẹ́ kan tí kò ṣíwọ́ ẹ̀bẹ̀

   

11:1-13

 

Ó fi ìka Ọlọ́run lé ẹ̀mí èṣù jáde; ó tún fún wọn ní àmì Jónà nìkan

   

11:14-36

 

Ó bá Farisí jẹun; ó dẹ́bi fún ìwà àgàbàgebè àwọn Farisí

   

11:37-54

 

Àwọn àpèjúwe: ọkùnrin ọlọ́rọ̀ tí kò lọ́gbọ́n nínú àti ti olóòótọ́ ìríjú náà

   

12:1-59

 

Ó wo obìnrin kan tó tẹ̀ kòlòbà sàn lọ́jọ́ Sábáàtì; àpèjúwe hóró músítádì àti ti ìwúkàrà

   

13:1-21

 

32, Àjọyọ̀Ìyàsímímọ́

Jerúsálẹ́mù

Àpèjúwe olùṣọ́ àgùntàn àtàtà àti agbo àgùntàn; àwọn Júù fẹ́ sọ ọ́ lókùúta; ó kọjá sí Bẹ́tánì ní ìsọdá Jọ́dánì

     

10:1-39