Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àfikún Ìsọfúnni Láti Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

 4-G

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá 1)

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá 1)
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

33, Nísàn 8

Bẹ́tánì

Jésù dé lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú Ìrékọjá

     

11:55–12:1

Nísàn 9

Bẹ́tánì

Màríà da òróró sí orí àti ẹsẹ̀ rẹ̀

26:6-13

14:3-9

 

12:2-11

Bẹ́tánì sí Bẹtifágè sí Jerúsálẹ́mù

Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ, ó gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́

21:1-11, 14-17

11:1-11

19:29-44

12:12-19

Nísàn 10

Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù

Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́; ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ lẹ́ẹ̀kan sí i

21:18, 19; 21:12, 13

11:12-17

19:45, 46

 

Jerúsálẹ́mù

Àwọn àlùfáà àgbà àtàwọn akọ̀wé gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù

 

11:18, 19

19:47, 48

 

Jèhófà sọ̀rọ̀; Jésù sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀; àsọtẹ́lẹ̀ tí Aísáyà sọ nípa àìgbàgbọ́ àwọn Júù ṣẹ

     

12:20-50

Nísàn 11

Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù

Ẹ̀kọ́ nípa igi ọ̀pọ̀tọ́ tó rọ

21:19-22

11:20-25

   

Jerúsálẹ́mù, tẹ́ńpìlì

Wọ́n béèrè ẹni tó fún Jésù láṣẹ; àpèjúwe ọmọkùnrin méjì

21:23-32

11:27-33

20:1-8

 

Àwọn àpèjúwe: àwọn aroko tó jẹ́ apànìyàn, àsè ìgbéyàwó

21:33–22:14

12:1-12

20:9-19

 

Ó dáhùn ìbéèrè nípa Ọlọ́run àti Késárì, àjíǹde, àṣẹ tó ga jù lọ

22:15-40

12:13-34

20:20-40

 

Ó bi àwọn èrò bóyá Kristi jẹ́ ọmọ Dáfídì

22:41-46

12:35-37

20:41-44

 

Ègbé fún àwọn akọ̀wé àtàwọn Farisí

23:1-39

12:38-40

20:45-47

 

Ó kíyè sí ohun tí opó kan fi ṣètọrẹ

 

12:41-44

21:1-4

 

Òkè Ólífì

Ó sọ àmì ìgbà tóun máa wà níhìn-ín

24:1-51

13:1-37

21:5-38

 

Àwọn àpèjúwe: wúńdíá mẹ́wàá, tálẹ́ńtì, àgùntàn àti ewúrẹ́s

25:1-46

     

Nísàn 12

Jerúsálẹ́mù

Àwọn aṣáájú Júù gbìmọ̀ pọ̀ láti pa á

26:1-5

14:1, 2

22:1, 2

 

Júdásì ṣètò bó ṣe máa fi í lé wọn lọ́wọ́

26:14-16

14:10, 11

22:3-6

 

Nísàn 13 (Ọ̀sán Thursday)

Ìtòsí àti nínú Jerúsálẹ́mù

Ó múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá tó ṣe kẹ́yìn

26:17-19

14:12-16

22:7-13

 

Nísàn 14

Jerúsálẹ́mù

Ó bá àwọn àpọ́sítélì jẹ Ìrékọjá

26:20, 21

14:17, 18

22:14-18

 

Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì

     

13:1-20