Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 4-F

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Lọ Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Pa Dà Lọ Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, lẹ́yìn Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́

Bẹ́tánì ní ìsọdá Jọ́dánì

Ó lọ síbi tí Jòhánù ti ń batisí àwọn èèyàn; ọ̀pọ̀ èèyàn gba Jésù gbọ́

     

10:40-42

Pèríà

Ó ń kọ́ni ní àwọn ìlú àti abúlé, ó ń lọ sí Jerúsálẹ́mù

   

13:22

 

Ó ní kí àwọn èèyàn gba ẹnu ilẹ̀kùn tóóró; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù

   

13:23-35

 

Ó lè jẹ́ ní Pèríà

Ó kọ́ni ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀; àwọn àpèjúwe: ibùjókòó ọlọ́lá àtàwọn tí wọ́n pè tó ń ṣàwáwí

   

14:1-24

 

Ronú lórí ohun tó máa náni láti di ọmọ ẹ̀yìn

   

14:25-35

 

Àwọn àpèjúwe: àgùntàn tó sọ nù, ẹyọ owó tó sọ nù, ọmọkùnrin tó sọ nù

   

15:1-32

 

Àwọn àpèjúwe: ìríjú aláìṣòótọ́, ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù

   

16:1-31

 

Ẹ̀kọ́ lórí ìkọsẹ̀, ìdáríjì àti ìgbàgbọ́

   

17:1-10

 

Bẹ́tánì

Lásárù kú, ó sì jíǹde

     

11:1-46

Jerúsálẹ́mù; Éfúráímù

Wọ́n dìtẹ̀ láti pa Jésù; ó kúrò níbẹ̀

     

11:47-54

Samáríà; Gálílì

Ó wo adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn; ó sọ bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa dé

   

17:11-37

 

Samáríà tàbí Gálílì

Àwọn àpèjúwe: opó tí kò ṣíwọ́ ẹ̀bẹ̀, Farisí àti agbowó orí

   

18:1-14

 

Pèríà

Ó kọ́ni nípa ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀

19:1-12

10:1-12

   

Ó súre fún àwọn ọmọdé

19:13-15

10:13-16

18:15-17

 

Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà; àpèjúwe nípa àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà àti owó iṣẹ́ wọ́n tó dọ́gba

19:16–20:16

10:17-31

18:18-30

 

Ó lè jẹ́ ní Pèríà

Ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ nígbà kẹta

20:17-19

10:32-34

18:31-34

 

Bíbéèrè ipò fún Jákọ́bù àti Jòhánù nínú Ìjọba Ọlọ́run

20:20-28

10:35-45

   

Jẹ́ríkò

Ó gba ibẹ̀ kọjá, ó wo àwọn ọkùnrin afọ́jú méjì sàn; ó lọ sọ́dọ̀ Sákéù; àpèjúwe mínà mẹ́wàá

20:29-34

10:46-52

18:35–19:28