WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

30

Gálílì

Ìgbà àkọ́kọ́ tí Jésù kéde pé “ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé”

4:17

1:14, 15

4:14, 15

4:44, 45

Kánà; Násárétì; Kápánáúmù

Ó mú ọmọ ẹmẹ̀wà kan lára dá; ó ka àkájọ ìwé Aísáyà; wọ́n kọ̀ ọ́; ó lọ sí Kápánáúmù

4:13-16

 

4:16-31

4:46-54

Òkun Gálílì, nítòsí Kápánáúmù

Ó pe ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin: Símónì àti Áńdérù, Jákọ́bù àti Jòhánù

4:18-22

1:16-20

5:1-11

 

Kápánáúmù

Ó mú ìyá ìyàwó Símónì àtàwọn míì lára dá

8:14-17

1:21-34

4:31-41

 

Gálílì

Ìrìn àjò àkọ́kọ́ ní Gálílì, pẹ̀lú ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin náà

4:23-25

1:35-39

4:42, 43

 

Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn; àwọn èrò tẹ̀ lé e

8:1-4

1:40-45

5:12-16

 

Kápánáúmù

Ó wo alárùn ẹ̀gbà kan sàn

9:1-8

2:1-12

5:17-26

 

Ó pe Mátíù; ó bá àwọn agbowó orí jẹun; wọ́n béèrè ọ̀rọ̀ nípa ààwẹ̀

9:9-17

2:13-22

5:27-39

 

Jùdíà

Ó wàásù nínú sínágọ́gù

   

4:44

 

31, Ìrékọjá

Jerúsálẹ́mù

Ó wo ọkùnrin aláìsàn tó wà ní Bẹtisátà sàn; Àwọn Júù ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á

     

5:1-47

Ó pa dà láti Jerúsálẹ́mù (?)

Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń ya erín ọkà jẹ lọ́jọ́ Sábáàtì; Jésù “Olúwa Sábáàtì”

12:1-8

2:23-28

6:1-5

 

Gálílì; Òkun Gálílì

Ó mú ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ lára dá lọ́jọ́ Sábáàtì; ọ̀pọ̀ èèyàn tẹ̀ lé e; ó wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn

12:9-21

3:1-12

6:6-11

 

Òkè nítòsí Kápánáúmù

Ó yan àpọ́sítélì méjìlá

 

3:13-19

6:12-16

 

Nítòsí Kápánáúmù

Ó ṣe Ìwàásù Lórí Òkè

5:1–7:29

 

6:17-49

 

Kápánáúmù

Ó wo ìránṣẹ́ ọ̀gá ẹgbẹ́ ọmọ ogun kan sàn

8:5-13

 

7:1-10

 

Náínì

Ó jí ọmọ opó kan dìde

   

7:11-17

 

Tìbéríà; Gálílì (Náínì tàbí itòsí)

Jòhánù tó wà lẹ́wọ̀n rán àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sí Jésù; ó yin Jòhánù

11:2-30

 

7:18-35

 

Gálílì (Náínì tàbí itòsí)

Obìnrin ẹlẹ́ṣẹ̀ kan da òróró sí ẹsẹ̀ rẹ̀; àpèjúwe nípa àwọn ajigbèsè

   

7:36-50

 

Gálílì

Ìrìn àjò kejì lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù, pẹ̀lú àwọn méjìlá

   

8:1-3

 

Ó lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde; ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì 12:22-37

12:22-37

3:19-30

   

Àmì Jónà nìkan ló fún àwọn èèyàn

12:38-45

     

Ìyá rẹ̀ àtàwọn àbúrò rẹ̀ wá; ó sọ pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn ni ẹbí òun

12:46-50

3:31-35

8:19-21