Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

 13

Àwọn Agbára Ayé tí Dáníẹ́lì Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Wọn

Àwọn Agbára Ayé tí Dáníẹ́lì Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Wọn
WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Bábílónì

Dáníẹ́lì 2:32, 36-38; 7:4

607 Ṣ.S.K. Nebukadinésárì Ọba pa Jerúsálẹ́mù run

Mídíà àti Páṣíà

Dáníẹ́lì 2:32, 39; 7:5

539 Ṣ.S.K. Wọ́n ṣẹ́gun Bábílónì

537 Ṣ.S.K. Kírúsì pàṣẹ pé káwọn Júù pa dà sí Jerúsálẹ́mù

Gíríìsì

Dáníẹ́lì 2:32, 39; 7:6

331 Ṣ.S.K. Alẹkisáńdà Ńlá ṣẹ́gun Páṣíà

Róòmù

Dáníẹ́lì 2:33, 40; 7:7

63 Ṣ.S.K. Ó ṣàkóso ilẹ̀ Ísírẹ́lì

70 S.K. Ó pa Jerúsálẹ́mù run

Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà

Dáníẹ́lì 2:33, 41-43

1914 sí 1918 S.K. Nígbà Ogun Àgbáyé Kìíní, Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso