WÒÓ
Ọ̀rọ̀
Àwòrán

Àwọn Ohun Tó Wà ní Àgọ́ Ìjọsìn

 1. Àpótí(Ẹk 25:10-22; 26:33)

 2. Aṣọ Ìkélé (Ẹk 26:31-33)

 3. Ọwọ̀n fún Aṣọ Ìkélé (Ẹk 26:31, 32)

 4. Ibi Mímọ́ (Ẹk 26:33)

 5. Ibi Mímọ́ Jù Lọ (Ẹk 26:33)

 6. Àtabojú (Ẹk 26:36)

 7. Ọwọ̀n fún Àtabojú (Ẹk 26:37)

 8. Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Ìtẹ̀bọ̀ Tí Wọ́n Fi Bàbà Ṣe (Ẹk 26:37)

 9. Pẹpẹ Tùràrí (Ẹk 30:1-6)

 10. Tábìlì Búrẹ́dì Àfihàn (Ẹk 25:23-30; 26:35)

 11. Ọ̀pá Fìtílà (Ẹk 25:31-40; 26:35)

 12. Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Ọ̀gbọ̀ Ṣe (Ẹk 26:1-6)

 13. Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Irun Ewúrẹ́ Ṣe (Ẹk 26:7-13)

 14. Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Àgbò Ṣe (Ẹk 26:14)

 15. Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Séálì Ṣe (Ẹk 26:14)

 16. Férémù (Ẹk 26:15-18, 29)

 17. Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Ìtẹ̀bọ̀ Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe, Tó Wà Lábẹ́ Férémù (Ẹk 26:19-21)

 18. Ọ̀pá Gbọọrọ (Ẹk 26:26-29)

 19. Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Ìtẹ̀bọ̀ Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe (Ẹk 26:32)

 20.   Bàsíà Tí Wọ́n Fi Bàbà Ṣe (Ẹk 30:18-21)

 21. Pẹpẹ Ọrẹ Ẹbọ Sísun (Ẹk 27:1-8)

 22. Àgbàlá (Ẹk 27:17, 18)

 23. Ẹnu Ọ̀nà (Ẹk 27:16)

 24. Àwọn Aṣọ Ìkélé Alásorọ̀ Tí Wọ́n Fi Aṣọ Ọ̀gbọ̀ Ṣe (Ẹk 27:9-15)

Àlùfáà Àgbà

Ẹ́kísódù orí 28 ṣàlàyé bí aṣọ àlùfáà àgbà ní Ísírẹ́lì ṣe rí

 • Láwàní (Ẹk 28:39)

 • Àmì Mímọ́ ti Ìyàsímímọ́ (Ẹk 28:36; 29:6)

 • Òkúta Ónísì (Ẹk 28:9)

 • Ẹ̀wọ̀n (Ẹk 28:14)

 • Aṣọ Ìgbàyà Ìdájọ́ Tó Ní Òkúta Iyebíye 12 (Ẹk 28:15-21)

 • Éfódì àti Àmùrè Tí Wọ́n Hun (Ẹk 28:6, 8)

 • Aṣọ Àwọ̀lékè Aláwọ̀ Búlúù Tí Kò Lápá (Ẹk 28:31)

 • Ìṣẹ́po Etí Aṣọ Tí Wọ́n So Agogo àti Pómégíránétì Mọ́ Yí Ká (Ẹk 28:33-35)

 • Aṣọ Oníbátànì Igun Mẹ́rin Tí Wọ́n Fi Aṣọ Ọ̀gbọ̀ Àtàtà Hun (Ẹk 28:39)